News

Awọn mejeji jẹ ori ade to ṣe pataki ni Naijiria. "Nigba ti mo wa nipo Aarẹ Naijiria, igbimọ awọn lọbalọba fi Sultan ati Ooni jẹ alaga – nibi ti Sultan ti n ṣoju iha Ariwa ...
Ọdun 2024 to kọja yii ni ileeṣẹ ọmọ ogun Russia padanu ọmọ ogun to pọ julọ ninu ogun rẹ pẹlu Ukraine. Eeyan 45,287 ni Russia padanu sinu ogun naa lọdun ọhun nikan ...