News

Awọn mejeji jẹ ori ade to ṣe pataki ni Naijiria. "Nigba ti mo wa nipo Aarẹ Naijiria, igbimọ awọn lọbalọba fi Sultan ati Ooni jẹ alaga – nibi ti Sultan ti n ṣoju iha Ariwa ...